Oùnjẹ wíwá Yorùbá jẹ oúnjẹ ti o pọju ti ó sì ní onírúurú tí i ṣe ti àwọn eniyan ilẹ̀ Yorùbá(àwọn agbègbè Yorùbá ní Nigeria). Lára àwọn oúnjẹ ìlúmọ̀ọ́ká Yorùbá nì wọ̀n yìí; Ọ̀fadà, Àsáró, Mọ́í Mọ́ì, Ọbẹ̀ Ẹ̀̀gúsí , Àbùlà , Àkàrà , Ilá Alásèpọ̀, Ẹ̀fọ́ rírò pẹ̀lú Òkèlè, abbl.
Àsáró
Mọ́í-mọ́í
Ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí
Ìrẹsì Ọ̀fadà
Diẹ ninu awọn Díẹ̀ nínú àwọn oúnjẹ Yorùbá mìíràn ló wà nísàlẹ̀ yìí:
Díẹ̀ nínù àwọn oúnjẹ Yorùbá:
1. Àkàrà
2. Àsun
3. Ọ̀ fadà
4. Àbùlà
5. Àsáró
6. Èkuru/Ofúlójú
7. Ekusu/Ṣapala
8. Ẹ̀fọ́ rírò
9. Bọ̀ọ̀lì
10. Gízídòdò
11. Ìkọ́kọrẹ́/Ìfọ́kọrẹ́
12. Àdàlù
13. Mọ́í-mọ́í/Ọ̀lẹ̀lẹ̀
14. Ìrẹsì Ẹyin
15 . Ìrẹsì àti ọbẹ̀ ata díndín
16. Ayamase
17. Ẹ̀wàgọ̀yìn
18. Ewédú
19. Ṣọkọ
20. Òkèlè (Iyán , Ẹ̀bà, Láfún, Àmàlà /Ọkà, Fùfú , Púpúrú etc.)
21. Ilà alásèpọ̀
22. Dòdò-Ìkirè
23 Ègbo àti Ẹ̀wà
24. Gúre ọlọ́bọ̀rọ́
25. Kókóró
26. Gúgúrú àti ẹ̀pà
27. Àádùn
28. Mósò
29. Jọ̀lọ́ fù
30. Ẹ̀gúsí
31. Ìpékeré
32. Dùn Dún Oníyẹ̀rì
33. Wàrà
34. Ẹ̀fọ́ Tẹ̀tẹ̀
35. Sisí pẹlẹbẹ
36. Ìrẹsì díndín)
37. Bàbá dúdú
38. Ọbẹ̀ irú
39. Dòdò
40. Ẹ̀kọ
41. Ògì
42. Àp ọ̀n
43. Ẹ̀gúsí Ìjẹ̀bú
44. Gurundi
45. Búrẹ́dì Agége
46. Ìrẹsì alágbọn
47. Gúre
48. Ọbẹ̀ ẹja díndín
49. Márúgbó àti púpùrú
50. Èbìrìpò
51. Iṣu àti ẹyin
52. Dùndún
53. Ọbẹ̀ ata Búkà
54. Sùpàgẹ́tì oní jọ̀lọ́fù
55. Àgbàdo sísun
56. Ìgbín díndín
57. Zóbò
58. Ògi bàbà
59. Gbẹ̀gìrì
60. Róbó
61. Ẹmu
62. Ilá àti ọbẹ̀ díndín
63. Gàrrí
64. Ọ̀gbọ̀lọ̀/oro
65. Iṣu àti ọbẹ̀ díndín
66. Amẹ́yidùn
67. pọfu pọfu
68. Ṣápùmáànì
69. Bọ́ùnsì
70. Àgbàdo àti àgbọn
71. Ẹyin Awó
72. Mọ́ímoí elépo
73. Àkàrà elépo
74. Iṣu sísun
75. Àkàrà Ẹ̀gùdí
76. Ọkà bàbà
77. Tìnkó
78. Esunsun
79. Èékánná Gowon
80. Ewédú Ẹ̀lẹ́gúsí
81. Ẹ̀wà Pakure
82. Ẹ̀fọ́ Ẹlẹ́gúsí
83. Báléwá
84. Búgan
85. Alàpà / Jogi
86. Ìṣápá
87. Kundi
88. Ọ̀jọ̀jọ̀
89. Bẹ́síkẹ́ / Wàrà
90. Àbàrí
91. Páfun
92. Ilá àti ọbẹ̀ ata
93. Pọfu pọfu
94. Ìgbín pẹ̀lú Ọbẹ̀ ata
95. Ànọ̀mọ́/Ọ̀dùnkún
96. Ob ẹ̀ Ọ̀fadà
97. Ọbẹ̀ Adìyẹ
98. Ìlasà
99. Àkàrà Kèngbè
98. Àkàrà Kókò
99. súrú
100. Ẹ̀kọ Eléwé
101. Jálókè/jáálòkè
102. Lápata / Ìpékeré
103. Ọbẹ̀ ilá funfun
104. Àbùlà
105. Luru
106. Ọ̀runlá
107. Ìmóóyò
108. Ẹ̀fọ́( Ṣọkọ, gbagba, Ebòlò, Yanrin, Odu, Wọ́rọ́wọ́, Tẹ̀tẹ̀, Gúre, Ajẹ́fáwo, Ìyànà-Ìpájà)
109. Mọ́í Mọ́í Ẹlẹ́mí Méjì
110. Yọyọ
111. Ọbẹ̀ Ẹyin