Odò Límpopó gbera ni aringbongan apaguusu Afrika, o si unsan lo si owo ilaorun de inu Okun India. O gun to bi 1,750 kilometres (1,087 mi), pelu itobi adogun omi 415,000 square kilometres (160,200 sq mi).
Itokasi
Coordinates: 25°10′S 33°35′E / 25.167°S 33.583°E / -25.167; 33.583