Night Dancer |
Olùkọ̀wé | Chika Unigwe |
---|
Country | Nigeria |
---|
Language | English |
---|
Genre | Fiction |
---|
Publisher | Jonathan Cape |
---|
Publication date | 7 June 2012 |
---|
Pages | 272 |
---|
ISBN | Àdàkọ:ISBNT |
---|
Night dancer je ìwé ti Chika Unigwe kọ ní ọdún 2012.[1][2] Ìwé náà tẹ̀lé ẹ̀dá-ìtàn Mma, lẹ́yìn tó sin ìyá rẹ̀, ó jogún àwọn ohun ìní ìyá náà àti àwọn ìdàmú tí ìyà rẹ̀ dojúkọ sẹ́yìn. Mma pinnu láti tu àwọn àṣírí ìdílé náà àti ìdánimọ̀ òun gan-an alára. Ìbùdó ìtàn náà jẹ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ní àádọ́ta ọdún sẹ́yìn, ìwé ìtàn-àròsọ náà dá lórí orí-ọ̀rọ̀ ìdílé, ojúṣe, àti ìsopọ̀ tó wà láàárín àwọn ọmọ àti àwọn ọmọbìnrin, èyí tí ó fa àyẹ̀wò àti ìlàkàkà láti bọ́ nínú ìṣòro.
Idite Lakotan
Àwọn ìtọ́kasí