Nigerian Defence Academy tabi Ile-eko Oro Abo Naijiria ni yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fun awon omo-ologun to wa ni ilu Kaduna[1][2]. Akoko ikẹẹkọ Ile-eko Oro Abo Naijiria jẹ ọdun marun (Ọdun mẹrin fun ti akadẹmi ati ọdun kan fun ti ologun)[3].
Itan
Ile-ẹkọ ọrọ abo Naigiria ni a dasilẹ ni óṣu February, ọdun 1964[4] gẹgẹbi atunṣè ti ilẹ british lati ṣè akoso ikẹẹkọ ti ólógun collẹgi RMFTC ti wọn pada sọ ni collẹgi ikẹẹkọ ologun ti ilẹ Naigiria ta mọsi NMTC ni ọjọ ti órilẹ ede naa gba óminira. Ilẹ ẹ̀kọ ologun kọ awọn óṣiṣè ti ologun, awọn ologun to mojuto omi ati awọn ologun to mojuto oke ofurufu[5][6].
Yara Ikawe ti Akadẹ̀mi
Yara Ikawe Ilẹ ẹkọ ọrọ abo jẹ ọkan gbogi fun ikọni ati ikẹẹkọ ti ologun. Yara Ikawe ti akadẹmi naa ni a da silẹ̀ ni ọdun 1963 lati gbe ikẹẹkọ larugẹ[7]. Oluṣakoso yara ikawe naa lọwọ ni Umar Lawal[8].
Awọn Ọgágun
- Brigadier M.R. Varma (1964 – 1969) (Ọgagun akọkọ ti apapọ ilẹ India ti Ilẹ-ẹkọ abo)
- Alabojuto ologun David Ejoor (Óṣu January, Ọdun 1969 – Ọdun 1971) (Ọgagun akọkọ ti Ilẹ-ẹkọ abo ti ilẹ Naigiria)
- Alabojuto ologun Robert Adeyinka Adebayo (Ósu January, Ọdun 1971 – Óṣu March, Ọdun 1971)
- Alabojuto ologun Eyo Okon Ekpo (Óṣu March, Ọdun 1971 – Óṣu February, Ọdun 1975)
- Brigadier Illiya Bisalla (Óṣu February, Ọdun 1975 – Óṣu August, Ọdun 1975)
- Brigadier Gibson Jalo (Óṣu August, Ọdun 1975 – Óṣu January, Ọdun 1978)
- Brigadier E.S. Armah (Óṣu January, Ọdun 1978 – July 1978)
- Brigadier Joseph Garba (Ósu July 1978 – Óṣu July Ọdun 1979)
- Brigadier Zamani Lekwot (Ósu July 1979 – Ọdun 1982)
- Brigadier Abdullahi Shelleng (1982 – Ósu January Ọdun 1984)
- Alabojuto ologun Paul Tarfa (Ósu January 1984 – Ọdun 1985)
- Alabojuto ologun Peter Adomokai (Ọdun 1986 – Ọdun 1988)
- Alabojuto Ajagun Salihu Ibrahim (Ọdun 1988 – Ọdun 1990)
- Alabojuto Ajagun Garba Duba (Ọdun 1990 – Ósu February Ọdun 1992)
- Alabojuto Ajagun Aliyu Mohammed Gusau (Óṣu February 1992 – Óṣu January Ọdun 1993)
- Alabojuto Ajagun Mohammed Balarabe Haladu (Óṣu January Ọdun 1993 – Ọdun 1994)
- Alakoso Oṣiṣẹ Ile-Ọrun Al-Amin Daggash (Ọdun 1994 – Óṣu June Ọdun 1998)
- Alabojuto ologun Bashir Salihi Magashi (Óṣu June 1998 – 1999)
- Alabojuto ologun Thaddeus Ashei (2000 – 2002)
- Alabojuto ologun Okon Edet Okon (2002 – 2003)
- Alabojuto ologun Patrick Ademu Akpa (2003 – 2004)
- Alabojuto Ajagun Abel Akale (2004 – 2006)
- Alabojuto ologun Harris Dzarma (2006 – Óṣu August 2008)
- Alabojuto ologun Mamuda Yerima (Óṣu August 2008 – Óṣu August 2010)
- Alabojuto ologun Emeka Onwuamaegbu (Óṣu August 2010 – Óṣu December 2013)[7]
- Alabojuto ologun Muhammad Inuwa Idris (Óṣu December 2013 – Óṣu August 2015)
- Alabojuto ologun Mohammed Tasiu Ibrahim (Óṣu August 2015 – Óṣu October 2017)
- Alabojuto ologun Adeniyi Oyebade (Óṣu October 2017 – Óṣu November 2019)
- Alabojuto ologun Jamilu Sarham (Óṣu November 2019 – Óṣu March 2021)
- Alabojuto ologun Sagir Yaro (Óṣu March 2021 – Óṣu April 2021)
- Alabojuto ologun Ibrahim Manu Yusuf (Óṣu April 2021 titi di isin)[9][10]
Itokasi