Nia Long |
---|
Long in 2012. |
Ọjọ́ìbí | 30 Oṣù Kẹ̀wá 1970 (1970-10-30) (ọmọ ọdún 54) Brooklyn, New York, United States |
---|
Iṣẹ́ | Dancer, actress |
---|
Ìgbà iṣẹ́ | 1986–present |
---|
Alábàálòpọ̀ | Ime Udoka |
---|
Nitara Carlynn Long (ojoibi October 30, 1970) je onijo ati osere ara Amerika. O gbajumo fun ipo re ninu ere ori telifisan bi The Fresh Prince of Bel-Air ati Third Watch, ati awon filmu Boyz n the Hood, Boiler Room, Soul Food, Love Jones, The Best Man, Big Momma's House, ati Are We There Yet?.
Itokasi