Khalifa bin Zayed bin Sultan Al Nahyan to je Sheikh (Lárúbáwá: خليفة بن زايد بن سلطان آل نهيان), (ojoibi 1948), ti won unpe ni Sheikh Khalifa ni Aare orile-ede awon Emirati Arabu Ajepiparapo (UAE) ati emiri ilu Abu Dhabi lowolowo. O bo si ipo mejeji na ni 3 November 2004, nigba to dipo baba re Zayed bin Sultan Al Nahyan, to ku ni ojo kan seyin ojo na.
Itokasi