Joe Biden |
---|
|
|
46th President of the United States |
---|
Lọ́wọ́lọ́wọ́ |
Ó gun orí àga January 20 2021 |
Asíwájú | Donald Trump |
---|
United States Senator from Delaware |
---|
In office January 3, 1973 – January 15, 2009 |
Asíwájú | Caleb Boggs |
---|
Arọ́pò | Ted Kaufman |
---|
Chairman of the Senate Committee on the Judiciary |
---|
In office January 6, 1987 – January 3, 1995 |
Asíwájú | Strom Thurmond |
---|
Arọ́pò | Orrin Hatch |
---|
Chairman of the International Narcotics Control Caucus |
---|
In office January 4, 2007 – January 3, 2009 |
Asíwájú | Chuck Grassley |
---|
Arọ́pò | Dianne Feinstein |
---|
Chairman of the Senate Committee on Foreign Relations |
---|
In office January 4, 2007 – January 3, 2009 |
Asíwájú | Richard Lugar |
---|
Arọ́pò | John Kerry |
---|
In office June 6, 2001 – January 3, 2003 |
Asíwájú | Jesse Helms |
---|
Arọ́pò | Richard Lugar |
---|
In office January 3, 2001 – January 20, 2001 |
Asíwájú | Jesse Helms |
---|
Arọ́pò | Jesse Helms |
---|
Member of the New Castle County Council |
---|
In office 1970 – 1972 |
|
Àwọn àlàyé onítòhún |
---|
Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kọkànlá 1942 (1942-11-20) (ọmọ ọdún 82) Scranton, Pennsylvania |
---|
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic Party |
---|
(Àwọn) olólùfẹ́ | Neilia Hunter (deceased; m. 1966 – 1972) Jill Jacobs (m. 1977) |
---|
Àwọn ọmọ | Beau Biden Robert Hunter Biden Naomi Christina Biden Ashley Blazer Biden |
---|
Residence | Number One Observatory Circle (Official) Wilmington, Delaware (Private) |
---|
Alma mater | University of Delaware (B.A.) Syracuse University College of Law (J.D.) |
---|
Profession | Lawyer |
---|
Signature | |
---|
Website | https://whitehouse.gov/administration/president-biden/ |
---|
Joseph Robinette Biden Jr.(tí a bí ní November 20, 1942)[2] jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Amerika àti Ààrẹ Amẹ́ríkà lọ́wọ́ lọ́wọ́. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òsèlú "Democratic Party". Óun ni ìgbàkejì ààrẹ orílè-èdè Amerika láàrin ọdún 2009 sí 2017 lábé isejoba Ààrẹ Barack Obama, òun sì ni Senato tí ó ṣe asoju Delaware láàrin ọdún 1973 sí ọdún 2009.
Wọ́n bi sí Scranton, Pennsylvania, ó sì padà kó lọ Delaware ní ọdun 1953. Ó kàwé ní Yunifásitì ti Delaware kí ó tó tesiwaju ní Yunifásitì Syracuse láti gbami eye ìmò òfin.
Àwọn Ìtókasí