Ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ìtàkùn ìbára-ẹni sọ̀rọ̀ tí a lè ṣe ìkékúrú rẹ̀ sí (TSP) jẹ́ ilé iṣẹ́ tí ó eà ní ọ̀nà bí a ṣe lè rí ara ẹni bá sọ̀rọ́, yálà nípa lílo ẹ̀rọ ìpè ìléwọ́, tàbí ìtàkùn ayélujára. [1]
[2]
Ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ìtàkùn ìbára-ẹni sọ̀rọ̀ tàbi
TSPs, ni ó jẹ́ wípé nígbà kan rí, ìjọba orílẹ̀-èdè nìkan ló ma ń ṣàkóso lórí pípèsè irúfẹ́ ohun èlò ìbára-ẹni sọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀ nítorí owó tabua tí ó má ń náni láti pèsè rẹ̀. Àmọ́ nkan ti yí padà tí àwọn ilé-iṣẹ́ aládàáni náà ti ń pèsè àwọn ohun èlò yí. [3]
Àwọn Ìtọ́kasí