Ilé iṣẹ́ Rédíò ìpínlẹ̀ Ogùn tí ìgé kúrú rẹ̀ jẹ́ OGBC jẹ́ ilé iṣẹ́ ìjọba ti Ìpínlẹ̀ Ògùn
[1]
Olú ilé iṣẹ́ náà fìdí kalẹ̀ sí Ìbarà ní ìlú Abẹ́òkútatí ó jẹ́ olú ìle ìpínlẹ̀ Ògun ní apá ìwọ̀ Oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà . Orì ìkànì 90.5FM àti 92.80 ni wọ́n ti ń gbóhùn sáfẹ́fẹ́. Wọ́n dá ilé iṣẹ́ náà kalẹ̀ ní ojọ́ Kejì oṣù Kejì, ọdún 1977 (February 2, 1977) gẹ́gẹ́ bí ilé isẹ́ rédíò ti ìjọba.[2]
Ẹ tún le wo
Àwọn ìtọ́ka sí