Idris Legbo Kutigi (ojoibi 31 December, 1939) je agbejoro ati adajo omo ile Naijiria lati ilu Kutigi, ni Ipinle Niger. Ohun ni Onidajo Agba fun Ile Ejo Togajulo ile Naijiria lati 30 January, 2007 titi di oni.
Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.
Strategi Solo vs Squad di Free Fire: Cara Menang Mudah!