Friedrich Engels |
---|
Friedrich Engels |
Orúkọ | Friedrich Engels |
---|
Ìbí | 28 November 1820 Barmen, Prussia |
---|
Aláìsí | 5 August 1895(1895-08-05) (ọmọ ọdún 74) London, England
|
---|
Ìgbà | 19th-century philosophy |
---|
Agbègbè | Western Philosophy |
---|
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | Marxism |
---|
Ìjẹlógún gangan | Political philosophy, Politics, Economics, class struggle, capitalism |
---|
Àròwá pàtàkì | Co-founder of Marxism (with Karl Marx), alienation and exploitation of the worker, historical materialism |
---|
Ipa látọ̀dọ̀
Kant, Hegel, Feuerbach, Stirner, Smith, Ricardo, Rousseau, Goethe, Fourier, Hess, Morgan
|
|
Ìtọwọ́bọ̀wé | |
---|
Friedrich Engels (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈɛŋəls]; 28 November 1820 – 5 August 1895) je omo Jemani onimosayensi awujo, oludako, oludero oloselu, onimo oye, ati baba ero komunisti, pelu Karl Marx. Awon mejeji ni won ko Manifesto Komunisti ni 1848. Engels si tun solotu iwe keji ati iketa Das Kapital leyin iku Marx.
Itokasi