Edgar Douglas Adrian nịọgbọ́njo osu kọkànlá Ọdún 1889 (11-30-1889). A bi I ni ilú Hampstead, London, England. O kú ní ọjọ́ kẹ̣rin oṣú kẹjọ ọdún 1977 (ní ìgbà naa o jẹ́ ọmọ dun mẹ́ta-di-ni-aadọrun-un).
O jẹ́ ará ìlu British tí o jẹ́ onímọ ifero mo-ise-ohun-ẹlẹ́mi ati ólùgbà ebùn íyibíye ọlọ́lá ni ọdún 1932 fún ìmọ ìse ohun ẹlẹmi ti oun àti Sir Charles Sherrigbon jùmọ̀ jẹ́ fún ìmúlò oun kan nínú ara tí o má gbé ìròyin làtí ibi opolo de ibi-ti-o kú lárá.
Ọmọ Alfred Douglas Adrian, onimọran ofin fún igbimọ ijọba ibíle tí BriitiṣI (British) ni ojogbon Edgar je. Ọ̀jọ̀gbọ́n Edger Adrian lo si ile-ìwe West Minister, o si ká sáyẹ́ǹsì adándá ni ilé-ìwé gíga ti Kémíbiriijì. O si wa ni ibè fún opolopo odun.
O parí kí kọ́ ìmọ̀ egbógi ni ọdun 1915. Iṣé aseparí fun eko wọn ti ile-wosan ni o se ni ile-Iwosan ti St. Bartholemew’s ni London nigba ogun agbaye kiini, O se ìtọ́jú àwọn ológun. Ọ̀jọgbọ́n Edger pada si Kémíbirììji ní ọdun 1919, ni igba ti o di ọdun 1925.
Ọ̀jọ̀gbọ́n Adrian Baron fẹ́ Arabirin HESTER AGNES PINSENT ni ọjọ́ ḳẹrin-la osu kẹta ọdun 1923 (14-6-1923). Won bi ọmọ mẹ̣́ta (ọmọ obinrin kan àti awọn Ibejí miiran). Ọ̀jọ̀gbọ́n Adrian se awárì elétirìiki nínú ẹ̀yá ara níbí isan.
Itokasi
|
---|
1901–1925 | |
---|
1926–1950 | |
---|
1951–1975 | |
---|
1976–2000 | |
---|
2001–present | |
---|
|