Dubai (Pípè: /duːˈbaɪ/ doo-BYE; Lárúbáwá: دبيّ dubayy) je ikan ninu awon emireti meje to wa ni United Arab Emirates (UAE). O budo si guusu Ikun-omi Persia lori Arabian Peninsula ohun sini o ni olugbe totobijulo pelu aala ileagbegbe totobijulo larin gbogbo awon emireti leyin Abu Dhabi.[5] Dubai ati Abu Dhabi ni emireti meji pere ti won ni agbara idina lori awon oro pataki ni ileasofin.[6]
Itokasi