Charlize Theron (General American English pronunciation:
/ʃɑrˈliːs ˈθɛrən/; Afrikaans pronunciation: Àdàkọ:IPA-af;[1] ojoibi 7 August 1975) je osere ati ologe aso ara Guusu Afrika[2] to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Todarajulo.
Ìbéèrè pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
Wọ́n bíi Theron sì ìlú Benoni ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà, òun nìkan sì ni àwọn òbí rẹ bí.[3][4]
Ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹfà, ọdún 1991, bàbà Theron tí ó jé ọ̀mùtí gbèrò láti pa Charlize àti ìyá rẹ,[5] o yín ìbon fún wọn, ṣùgbọ́n kò bá wọn, ìyá Charlize bá gbé ìbon tirè ó sì fi pá ọkọ rẹ̀.[6] Ilé ẹjọ́ dá láre, nítorí pé ó fẹ́ pèsè abo fún ohun àti ọmọ rẹ̀.[7][8]
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ tí Putfontein Primary school[9][10][11][12] àti National School of Art ni ìlú Johannesburg.[13][14]
Iṣẹ́
Ó bere iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi oníjó, nígbà tí ó wa ni ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún, ó gbà iṣẹ́ mọ́dẹ́lì ni ìdíje tí wọ́n ṣe ní Salerno,[15] èyí sì jẹ kó lọ sí ìlú Milan ni orílẹ̀ èdè Italy.[16] Lẹ́yìn tí ó parí iṣẹ́ mọ́dẹ́lì náà, ó lọ sí ilé New York City, níbẹ̀ sì ni ó ti kọ́ bí wọn ṣe jó, àmọ́ ó padà sèse ni orúkún rẹ̀, èyí sì fà á tí kò fi lè jọ mọ́.
Itokasi
|
---|
1928–1950 | |
---|
1951–1975 | |
---|
1976–2000 | |
---|
2001–present | |
---|