Charles Chukwuma Soludo (ojoibi 28 July, 1960) je ojogbon imo isuna, ohun si ni Gomina ati Alaga igbimo awon oludari Ile Ifowopamo Ijoba ile Naijiria lati 29 May, 2004 titi di 29 May, 2009. Ni ojo kesan osu kokanla odun 2021, Soludo to n soju egbe All Progressives Grande Alliance ni won kede gege bi olubori ninu ibo gomina ipinle Anambra ni odun 2021, ti o si bori awon to sunmo re lati egbe PDP ati APC, Valentine Ozigbo ati Emmanuel Nnamdi Uba.
Itokasi