Charles Nohuoma Rotimi (tí wọ́n bí ní ọdún 1957) jẹ́ olùdarí àgbà ní National Institutes of Health (NIH) Ó ṣe ìdásílẹ̀ African Society of Human Genetics ní ọdún 2003. Rotimi kó ipa ribiribi nínú ìṣẹ̀dá Human Heredity and Health in Africa (H3Africa) pẹ̀lú ìrànwọ́ NIH àti Wellcome Trust. Wọ́n yàn án sínú ẹgbẹ́ National Academy of Medicine ní ọdún 2018.[1][2]
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ Morris, Kelly (2010-10-23). "Charles Rotimi: engaging Africa in human genomic research" (in English). The Lancet 376 (9750): 1383. doi:10.1016/S0140-6736(10)61943-5. ISSN 0140-6736. PMID 20971351.
- ↑ "Charles N. Rotimi, Ph.D.". genome.gov. NHGRI. Retrieved 2019-05-08.