Bola Ajibola |
---|
|
Minister of Justice of Nigeria |
---|
In office September 12, 1985 – December 4, 1991 |
Arọ́pò | Clement Akpamgbo |
---|
Judge of the International Court of Justice |
---|
In office 1991–1994 |
Asíwájú | Taslim Elias |
---|
|
Àwọn àlàyé onítòhún |
---|
Ọjọ́ìbí | 22 Oṣù Kẹta 1934 (1934-03-22) (ọmọ ọdún 90) |
---|
Alma mater | University of London |
---|
Omoba Bolasodun Adesumbo "Bola" Ajibola KBE (tí a bí ní ọjọ́ méjìlélógún oṣù kẹta ọdún 1943 - Oṣu Kẹrin Ọjọ 8, Ọdun 2023) jẹ́ Adájọ́-àgbà-yányán àti Mínísítà ètò - ìdájọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 1985 sí 1991.[1] Ó tún jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn Adájọ́ nílé ẹjọ́ àgbáyé láti ọdún 1991 sí 1994.[2] Bákan náà, ó jẹ́ ọ̀kan lára Adájọ́ márùn-ún lórí àjọ apẹ̀tùsáwọ̀ ẹnubodè láàrin orílẹ̀-èdè Eritrea àti Ethiopia tí ilé ejò Permanent Court of Arbitratio yàn.
Àwọn Ìtọ́kasí