Assyria ni ile-oba to gbale si Oke odo Tigris, ni Mesopotamia (Iraq), to joba lori awon opo ile obaluaye lopo igba. Oruko re wa lati oruko oluilu re akoko eyun ilu ayeijoun Assur (Akkadian: [𒀸𒋗𒁺 𐎹 Aššūrāyu] error: {{lang}}: text has italic markup (help); Arabiki: أشور[Aššûr] error: {{lang}}: unrecognized language tag: arLatn (help); Heberu: אַשּׁוּרAššûr, Aramaic: ܐܫܘܪAšur. Bakanna Assyria tun le je agbegbe jeografi tabi inu ibi ti awon ile obaluaye wonyi wa.