Ahmadu Umaru Fintiri (ojoibi October 27, 1967) ni gomina Ipinle Adamawa lowolowo [1] O fi tele je omo ile Igbimo Asofin Ipinle Adamawa, nibi ti won ti yan gege bi Olori Ile Asofin. O di aropo gomina Ipinle Adamawa fun igba die leyin igba ti gomina Murtala Nyako je yiyokuro lori ipo na ni July 2014,[2][3] ko to gbepo na fun Bala James Ngilari leyin to lo osu meta lori ibe.[4]
Itokasi