Al-Hajji Sir Ahmadu Ibrahim Bello (June 12, 1910 – January 15, 1966) ti òpòlopò mo sí sir Ahmadu Bello jé eni ti o wa nidi dida ariwa Nigeria kalè nipase ominira Nàìjíríà ni odun 1960. Oun si ni adari(Premier) àkókó ati enikan soso ti o di Premier ariwa Nàìjirià, ipò tí o di ipò náà mú títí ti won fi sékúpa ni odun 1966.
Òun tún ni adari Northern People's Congress, egbé òsèlú ti o wa ni ijoba nigba náà, àwon òtòkùlú Hausa-Fulani sì ni wón pò ni egbé òsèlú náà. Won kókó yan láti je asofin ní agbègbè ibi ti o wà kick to padà di minisita ijoba. O gbiyanju láti si Sultan Ìpínlè Sokoto kick to wo inú òsèlú.
Itokasi