Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Irepodun, Ìpínlẹ̀ Kwárà jé ìkan lara àwon agbegbe ìjoba ìpínlè mérìndilógún [1] tí o wa ni Naijiria, olú-ìlú rè ni Omu-aran, abajade eto ikaniyan 2006 ni pé agbegbe náà ní olugbe 147,594 [2].
Ara àwon ìlú agbegbe yí tí amo si ìlú Èsìé ní Èsìé Museum wa, Musiomu yí(tí o di dídá kale ni odun 1945) ni Musiomu àkókò tí a dakale ní orílè-èdè Nàìjirià [3]
Itokasi