Adeyemi Ambrose Afolahan |
---|
|
Alábójútó àkọ́kọ́ ìpínlẹ̀ Taraba |
---|
In office Ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹjọ Ọdún 1991 – Ọjọ́ kejì Oṣ̀ù kínín Ọdún 1992 |
Asíwájú | Abubakar Salihu (Gongola State) |
---|
Arọ́pò | Jolly Nyame |
---|
|
Àwọn àlàyé onítòhún |
---|
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kejìlá 1949 (1949-12-26) (ọmọ ọdún 75) Ibadan, Oyo State, Nigeria |
---|
Adeyemi Afolahan (bíi Ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá Ọdún 1947) jẹ́ alábójútó àkọ́kọ́ ìpínlẹ̀ Taraba, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n yàán ní ọdún 1991 lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n dá ìpínlẹ̀ Taraba sílẹ̀.[1][2][3]
Àwọn ìtọ́kasí