Àdàkọ:Ọdún2022, tí ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ọjọ́ Sátidé nínú kalẹ́ndà Gregori, ọdún 2022 ni ó ṣáájú ọdun 2023, òun sì ni ó ló tẹ̀lé ọdún 2021.
láti òsì lọ sí ilè(ní yíyí owó aago): Orita Yamato-Saidaiji ní wákàtí dí ẹ̀ lẹ́yìn ìgbà tí wón ṣe ikú pa Shinzo Abe; Ìwóde ifehonuhan lòdì sí ìjọba ní orílè-èdè Sri Lanka ni iwájú ilé Ààrẹ; Ní ọjọ́ kẹfà oṣù kàrún, ìbújáde àrùn Monkey pox béèrè ní United Kingdom; wọ́n gbé Èlísábẹ́tì kejì sí Westminster Hall fún àwọn ènìyàn láti fi ọ̀wọ̀ fun; ọmọ kan dúró sí àárín ilé tí ó ti dàwó ni orílẹ̀-èdè Afghanistan nígbà Ìmìtìtì ilẹ̀ tí ó ṣẹlẹ̀ ní Afghanistan ni osù kẹfà ọdún 2022; foto ibi kan ni ibi ayẹyẹ ìbẹ̀rẹ̀ 2022 Winter Olympics ní Beijing, China; Àwọn oluwode ni orita Aktobe nìgbà àìsinmi 2022 ti Kazakh; BMP-3(Ọkọ̀ ijagun) Rosia kan ni ẹ̀gbẹ́ Mariupol tí ó bàjẹ́ nígbà ìkógun Rosia wo Ukraine, odun 2022.
•Ní ọjó keje oṣù Kínní (January 7): Iye àwọn tí ó ti ní àrùn covid-19 kojá ọ̀ọ́dúnrúnr mílíọ́nù.[2]
•Ní ọjọ́ kẹwá oṣù Kínní (January 10): Fún ìgbà àkókò, àwọn Dókítá rí ỌkànẸlẹ́dẹ̀ gbé sínú ènìyàn, ó sì yè. Eléyìí ṣẹlẹ̀ ní Baltimore, Maryland ni orílè-èdè Amerika.[3]
•Ní ọjọ́ kẹtalélógún oṣù kínní (January 23): wọ́n fipá ggbàjọba lọ́wọ́ ààrẹ orílẹ̀-èdè Bùrkínà FasòRoch Kaboré, wọ́n sọ wípé ìdí tí àwọn fi gba ìjọba náà ni bí ààrẹ náà ṣe kùnà láti panọ́ làásìgbò kọ̀ọ̀kan tí àwọn igun ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí kan ń dá sílẹ̀ wà lára ìdí tí wọ́n fi yọ ọ́ kúrò nìpò.[3]
•Ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kíní (Jan 28): Iye abẹ́rẹ́ àjẹsára àrùn covid-19 tí àwọn ènìyàn ti lò lágbàáyé ti lé ní bílíọ́nù mẹ́wá .[2]
•Ní ọjọ́ kọkandínlọ́gbọ̀n oṣù kínní (Jan 29): Wọ́n dìbò yan ààrẹ orílẹ̀-èdèItaly, Sergio Mattarela fún sáà kejì ìjọba. [4]
•Ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì (26 Feb): Orílẹ̀-èdè Rọ́síà bẹ̀rẹ̀ sí ń kógun ja orílẹ̀-èdè Ukraine.[3]
•Ní ọjọ́ keje oṣù kẹta (March 7): Iye àwọn tí o ti kú nítorí aàrùn Covid-19 lé ni mílíọ́nù mẹ́fà (6 million). [5]
•Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin (April 13): Iye àwon ti o ti ní aàrùn covid-19 lé ni Ẹẹdẹgbẹta millionu.[6]
•Ní ọjọ́ l3rìndínlógún oṣù kẹrin(April 24): Apá kejì ìdìbò orílè-èdè Faransé bẹ̀rẹ̀, ààrẹ Emmanuel Macron sì jáwé olúborí láti ṣe sáà kejì tí olùdíje kejì, Marine Le Pen sì fìdí èémí .[7]
•Ní ọjọ́ kẹfà oṣù karùn ún (6 May): Àjakálẹ̀ aàrùn Monkey Pox gbòde: Aàrùn Monkey Pox nẹ̀rẹ̀ sí ń tàn kálẹ̀, ijọ́ tí wọ́n sì rí ẹni àkọ́kọ́ tí ó ní àrùn yí ní ìlú London, orílè-èdè United Kingdom.[8]
•Ní ọjọ́ kẹsàn án oṣù karùn ún (9 May): Mínísítà àgbà orílẹ̀-èdè Sri Lanka, Mahinda Rajapaksa kọ̀wé fiṣẹ́ sílẹ̀ nítorí ìwọ́de lòdì sí àkóso rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí mínísítà Ranil Wickremesinghe ṣe bọ́ sí ipò náà lẹ́yìn ọjọ́ kẹta tí Mahinda kọ̀wé fiṣẹ́ sílẹ̀.[9]
°Idibo gbogboogbo ti orílè-èdè Kenya: A yan William Ruto gégé bi Ààre orílè-èdè Kenya, oun ni ààre karun orílè-èdè Kenya. O fi ídí olùtakò rè, Ralia Odinga remi.[18]
• Ijó kerinla osù Kejo(August 12): Afunrasi odaran kan, tí àún pe ní Hadi Matar gún Salmon Rushdie lobe ní òpòlopò ibi, Salmon Rushdie jé olùkòwé omo orílè-èdè Amerika mó United Kingdom tí a bi ní Orílè-èdè India, wón gbé afunrasi náà, ogbeni Hadi Matar lo ilé-ejó ní ojó kejì.[12]
• Ojó ketadinlogbon ti osù kejo si ojó kokanla ti osù kesan(August 27-Sept 11): Won gbá copu Asia odun 2022 ní orílè-èdè United Arab Emirates, orílè-èdè Sri Lanka ló jáwé olúborí.[19]
• Ojó karun ti osù kesan(Sept 6): A yan Liz Truss gégé bi minisita àgbà fún orílè-èdè United Kingdom.[20]
• Ojo kejo ti osu Kesan(Sept 8) – Charles keta di oba United Kingdom àti orílè-èdè merinla mirán léyìn ìgbà tí Ayaba Elisabeti keji kú.[3]
• Ojo Kerinla si kerindinlogun osu kesan(September 14–16) – Ija wáyé Kyrgyzstan ati Tajikistan lori oro àlà, òpòlopò àwon omo ogun Kyrgyz ati Tajik ni oba isele náà lo.[16]
Ọjọ́ kerindinlogun oṣù Kesan(Sept 16) – Ìwóde ifehonuhan bẹ̀rẹ̀ ni orílẹ̀ èdè Iran lórí ikú ní akete àwọn Ọlọpa tó ún dojú kọ "ìwà kọòtọ̀".[21]
Ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kesan(Sept 19) – Ìsìnkú Èlísábẹ́tì kejì wáyé ní Westminster Abbey, London. Wọ́n sì gbé posi rẹ lọ sí Windor Castle lọ sin pẹ̀lú ọkọ àti òbí rẹ ni King George VI Memorial Chapel.[22]
Ọjọ́ kedogbon ti oṣù Kẹ̀sán(Sept 30): _Àwọn ológun Burkina Faso fi idite gba ìjọba, Ọ̀gá ológun Ibrahim Traore ni ó darí àwọn ológun yí. [23]
Ọjọ́ kẹfà oṣù Kẹ̀wá(Oct 6): Ọlọpa tẹ́lẹ̀ ri kan ṣekú pa àwọn ènìyàn merinlelogoji, èyí tí àwọn ọmọ mẹ́tàlélógún wà nínú wọn, ní ilé ìwé nosiri Na Klang district, orílè-èdè Thailand.[24]
Ọjọ́ karundinlogbon oṣù kewa(Oct 25) – Rishi Sunak di mínísítà àgbá tí orílẹ̀ èdè isokan gẹ̀ẹ́sì(United Kingdom) lẹ́yìn tí Liz Truss kọ̀wé fí ipò náà sílè.[25]
Ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kewa(Oct 28) - Elon Musk di alákóso ìtàkùn ayélujára Twitter lẹ́yìn tí ó rà á ní bilionu merinlelogoji dola.[26]
Ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kọkànlá(Nov 18) : Iye àwọn ènìyàn lagbaye pé bilionu mẹ́jọ [27]
Ìsèlè 2022 ní Nàìjíríà
Ijó kerin sí ijó kefa osù kinni(4-6 Jan): Àwon agbebon pa ènìyàn tó lé ni igba(200) ní ìpínlè Zamfara.[4]
Ijó kerinla sí ijó karunla osù kinni(14-15Jan): Àwon agbebon pa ènìyàn to lé ní Aadota(gegebi àwon iroyin kan se fi léde) ní ipínlè Kebbi, àwon olopa padà fi lede pé àwon ènìyàn mérìndilógún ni won pa, pèlú òpòlopò ti won ji gbé.[28][29]
Ojó karun ti osù kejì(5 Feb): Idibo àwon ìjoba ìbílè Kebbi waye.[30]
Ojo kewa ti osù kejì(10 Feb)
° Àwon agbebon pa ènìyàn marun ní ìlú Rogoji, Bakura ní ìpínlè Zamfara.[31] Iroyin gbe pé ìyá kan ti àwon vigilante pa omo refers níbí ní kí awon agbebon náà se nkan ti wón se.[32]
° Àwon olè agbebon kan se ìkolù sí moto tó ún gbodo kan, won pa ènìyàn mefa, olopa meji wà lara awon ti wón pa.[33]
Ojó kejìlá ti osù Kejì(12 Feb)- Idibo àwon ìjoba ìbílè Abuja ti odún 2022 wáyé.[34]
Ojó ketalelogun ti osù kejì(23 Feb) - Idibo ìjoba ìbílè ti ìpinlè Enugu fún odun 2022 wáyé.[35]
Ojó kejo ti osù keta(March 8): Àwon agbebon pa òpòlopò eniyan ní ìpínlè Kebbi.[36][37]
Ojó kéjìlá ti osù keta(March 12): Idibo awon ìjoba ìbílè Imo fún odun 2022.[38]
* Ojó kejidinlogbon ti osù keta(March 28): Àwon agbebon se ìkolù si oko oju irin kan ti óún lo láti Abuja sí Kaduna.[39]
Ojó kesan ti osù kerin(April 9): Idibo awon ìjoba ìbílè Adamawa wáyé.[40]
Ojó kèwá ti osù kerin(April 10): Àwon agbebon pa òpòlopò ní ìpinlè Plateau, won si tun ji òpòlopò gbé.[41]
Ojó kokanla ti osù kerin(April 11): Idibo àwon ijoba ìbílè ti Kastina wáyé.[42]
Ojó kéjìlá ti osù karun(12 May): Àwon kan sekú pa Deborah Yakubu tori wipe won ni o soro òdì sí Woli Mohammadu, wón soko lu pa, won sì tun dana sun.[43]
Ojó kejidinlogbon ti ojó karun(May 28): Awon eniyan kan tera won pa ni ibi tí ìjo kan ti ún pin ounje òfé ni ìlú Port Harcourt, ìpinlè Rivers.[44]
Ojó karun ti osù kefa(June 5): Àwon agbebon se ìkolù sí ijo kan ní ìlú Owo, ìpínlè Ondo, wón sì pa òpòlopò olùjósìn.[1]
Ojó kejidinlogun ti osù kefa(June 18): Idiboyan Gomina titun wáyé ni ìpinlè Ekiti.[45]
Ojó kerindinlogun ti osù keje(July 16): Idiboyan Gomina fun ìpínlè Osun wáyé.[46]
Ojó karundinlogbon osù keje(July 25): Tobi Amusan jáwé olubori ninú idije 100m hurdle. O gba àmì-èye golu.[47]
Ọjọ́ kẹjọ oṣù kewa(Oct 8): Ọ̀kẹ́rẹ́ jù, ènìyàn márùn-ún lé ní àádọ́rin pàdánù ẹ̀mí wọn nígbà tí ọ̀kọ̀ ojú omi kan yí sọ́dọ̀ ni ìpínlè Anambra.[48]
Ọjọ́ karundinlogbon oṣù kọkànlá(25 November) – gbajugbaja olórin èmi Sammie Okposo, ẹni tí ó jé ọmọ ọdún ọkàn lé li adota(51), fi ayé sílè. [49]
Ojó keje oṣù Kejìlá(7 Dec): Banki àpapò ti Nàìjíríà ti fi gbedeke owó tí ènìyàn lè gbà ní ọ̀sẹ̀ kan sí ọgọrun ẹgbẹrun Naira(100,000) láti dojú ìjà kọ ṣíṣe àwọn ayida owó àti gbígbé owó fún àwọn gbemogbemo.
Àwon ènìyàn tó papòdà ni 2022
Ojo kokanla osù kinni(11 Jan): Olori orílè-èdè Nàìjirià télèrí, Ernest Shonekan papòdà.[50]
Ojó kejilelogun ti osù kerin(22 April): Alafin Oyo, Oba Lamidi Adeyemi III fayé sílè.[51]
Ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹsàn(Sept 8): Èlísábẹ́tì II fayẹ́ sílè.[52]
Ìdíje ife-ẹ̀yẹ agbáyé ọdún 2022
Ogúnjọ́ oṣù kọkànlá ọdún 2022 ni ìdíje bọ́ọ̀lù àláfẹ̀sẹ̀gbá ti gbogbo àgbáyé wáyé orílẹ̀-èdè Qatar nígbà tí àwọn orílẹ̀-èdè méjìlélọ́gbọ̀n tí wọ́n pegedé jùlọ kópa nínú ìdíje ife ẹ̀yẹ agbáyé náà. Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n gbégbá orókè ni ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejìá ọdún 2022.
↑ 3.03.13.23.3"Man gets genetically-modified pig heart in world-first transplant". BBC News. 2022-01-11. Retrieved 2022-08-13.Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "BBC News 2022" defined multiple times with different contentÀṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "BBC News 2022" defined multiple times with different contentÀṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "BBC News 2022" defined multiple times with different content