Ìpínlẹ̀ Enugu (Igbo: Ȯra Enugu) jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè gúúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó pín ààlà sí àríwá pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Benue àti Ìpínlẹ̀ Kogi, Ìpínlẹ̀ Ebonyi sí ìlà-oòrùn àti gúúsù-ìlà-oòrùn, pínlẹ̀ Abia sí gúúsù, àti Ìpínlẹ̀ Anambra sí ìwọ̀-oòrùn. Ìpínlẹ̀ náà gba orúkọ rẹ̀ látara olú-ìlú rẹ̀ àti ìlú tí ó gbòòrò jù, tí ń ṣe Enugu.
Laaarin àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ìpínlẹ̀ Kogi jẹ́ ìpínlẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kọkàndínlọ́gbọ̀n tí ó gbòòrò jùlọ ní ààyè tàbí agbègbè àti ẹlẹ́ẹ̀kejìlélógún ní iye pẹ̀lú ènìyàn tí ó tó mílíọ́nnù mẹ́rin-àbọ̀dín-ni-díẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àbájáde ọdún 2016.[2][3]
Láyé òde-òní Ìpínlẹ̀ Enugu ní olùgbé láti bí ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn kúnfún àwọn oríṣiríṣi ẹ̀yà pẹ̀lú, pàápàá àwọn ará Igbo pẹ̀lú díẹ̀ wọn ti wọ́n jẹ́ àwọn ará Idoma àti Igala ní Etteh Uno.
Lẹ́yìn òmìnira ní ọdún 1960, agbègbè tí ó wá di Enugu báyìí wáà lára agbègbè ìlà-oòrùn tí wọ́n ti ní òmìnira títí di ọdún 1967 nígbàtí ekù náà pín tí agbègbè náà di apá kan ti Ìpínlẹ̀ àáríngbùngbùn ìlà-oòrùn.
Ninu ètò ọrọ̀-ajé, Ìpínlẹ̀ Enugu mú iṣẹ́ òwò ṣíṣe àti ọ̀gbìn lókùnkúndùn, pàápàá ọ̀pọ̀ isu, ìrẹsì, kókò, epo pupa, àti ẹ̀gẹ́. A key minor industry was mining, especially of coal in the Udi Hills around the city of Enugu. Ìpínlẹ̀ Enugu ní Ìtọ́ka Ìdàgbàsókè Ènìyàn ní ìdá kẹwàá tó ga jù lọ ní orílẹ̀-èdè, wọ́n sì kà á sí ọkàn nínú ilẹ̀ Igbo tí ó jẹ́ agbègbè ẹkù àṣà ẹ̀ya Igbo.[4]
Itokasi