Èdè Sípéènì |
---|
español, castellano |
Ìpè | /espaˈɲol/, /kast̪eˈʎano/ |
---|
Sísọ ní | (see below) |
---|
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | First languagea: 500 million a as second and first language 600 million. All numbers are approximate. |
---|
Èdè ìbátan | |
---|
Sístẹ́mù ìkọ | Latin (Spanish variant) |
---|
Lílò bíi oníbiṣẹ́ |
---|
Èdè oníbiṣẹ́ ní | 21 countries, United Nations, European Union, Organization of American States, Organization of Ibero-American States, African Union, Latin Union, Caricom, North American Free Trade Agreement, Antarctic Treaty. |
---|
Àkóso lọ́wọ́ | Association of Spanish Language Academies (Real Academia Española and 21 other national Spanish language academies) |
---|
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè |
---|
ISO 639-1 | es |
---|
ISO 639-2 | spa |
---|
ISO 639-3 | spa |
---|
|
Èdè Sípéènì (español tàbí castellano) jẹ́ èdè ní orílẹ̀-èdè Sípéènì, wọ́n sì sọ èdè yìí púpọ̀ ní àwọn orílẹ̀-èdè Apá Gúúsu Amẹ́ríkà. Èdè Sípéènì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Rómáńsì, àwọn èyí tí wọ́n fà yọ láti inú èdè Látìnì.
Itokasi