Àpáta jẹ́ ohun ribiti tí ó ń ṣẹlẹ̀ fúnra rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ohun àlùmọ́nì. Àpáta pín sí ọìsọ̀rí mẹ́ta pàtàkì jùlọ. Àwọn ni : igneous rocks, metamorphic rocks àti sedimentary rocks. Àpáta jẹ́ ohun tí ó fojú han jùlọ ní orí-ilẹ̀.[1]
Ẹ̀ka ìmọ̀ tí a ti ń kọ́ nípa àpáta, ìrúsókè ati àtòjọ rẹ̀ ni wọ́n ń pè ní Petrology ní èyí tí ó sì jẹ́ abala kan lára ẹ̀kọ́ ìmọ̀ nípa ilẹ̀ (geology).
[2]